ÈYÍ L'AWỌN TÓ GBÀ BỌỌLU S'ÁWỌ̀N JÙ NÍNÚ ÌDÍJE PREMIER LEAGUE - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, May 11, 2020

ÈYÍ L'AWỌN TÓ GBÀ BỌỌLU S'ÁWỌ̀N JÙ NÍNÚ ÌDÍJE PREMIER LEAGUE


Lọ́jọ́ kẹtàlá oṣù kẹta ọdún ni àjọ tó ń rí sì bọọlu alafẹsẹgba lagbaye, FIFA pàṣẹ wí pé kí gbogbo ìdíje ṣí lọ soko ìgbàgbé fún ìgbà díẹ̀ láti dẹ́kun itankalẹ aarun aṣekupani Covid-19.

Bi ẹ ṣe ń ka ìròyìn yìí, ó ṣeé ṣe kí idije náà bẹ̀rẹ̀ labẹle lọ́jọ́ kinni oṣù kẹfà ọdún yìí gẹ́gẹ́ bí ìjọba ṣe laa kalẹ lónìí ọjọ́ Aje, Mọnde.

Ju gbogbo rẹ lọ, èyí làwọn agbabọọlu tó ti gba góòlù wọlé sínú àwọ̀n ju. 

Jamie Vardy (Leicester) - Góòlù mọkandinlogun {19 goals} 

Pierre-Emerick Aubameyang (Arsenal) - Góòlù mẹtadinlogun {17 goals} 

Sergio Agüero (Manchester City) - Góòlù mẹrindinlogun {16 goals} 

Danny Ings (Southampton) - Góòlù mẹẹdogun {15 goals} 

Marcus Rashford (Manchester United) - Góòlù mẹrinla {14 goals} 

Tammy Abraham (Chelsea) - Góòlù mẹtala {13 goals} 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI