ỌGA KỌSITỌỌMU FẸ IYAWO TUNTUN, BONKẸLẸ NI WỌN ṢE-E - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, May 31, 2020

ỌGA KỌSITỌỌMU FẸ IYAWO TUNTUN, BONKẸLẸ NI WỌN ṢE-E


Ọga patapata fun ileeṣẹ aṣọbode lorilẹ-ede yii, Hameed Ali ti fẹ iyawo tuntun. Ilu Kano ni eto ayẹyẹ naa ti waye ni bonkẹlẹ.

Eyi waye lẹyin ọdun bii ọdun meji ti iyawo ẹ akọkọ, Hajiya Hadiza Jummai Ali ku nilu Abuja. Ọjọ kọkandinlọgbọn, oṣu kẹsan ọdun 2018 l'obinrin naa jade laye l'ọsibitu kan n'ilu Abuja.

ọmọ mẹrin la gbọ pe o wa laaarin wọn ko too di pe obinrin naa fi aye silẹ.

Fọto bi ayẹyẹ naa ṣe lọ lẹ n wo n'isalẹ yii.

 

 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI