ONILUPEJU TÍ ILUPEJU, ỌBA ADISA ODUNADE JÁDE LÁYÉ LÓJIJÌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, May 26, 2020

ONILUPEJU TÍ ILUPEJU, ỌBA ADISA ODUNADE JÁDE LÁYÉ LÓJIJÌ


Bó tilẹ̀ jẹ́ AWIKONKO kò tíì lè fìdí àṣírí ikú tó pá Onilupeju tí Ilupeju, Alayeluwa, Ọba Usman Adisa Ọdúnadé múlẹ̀ lasiko taa kọ ìròyìn yìí tán, ṣùgbọ́n gbogbo àwọn ará ìlú Ilupeju tó wà nijọba ìbílẹ̀ Ifẹlodun, ipinlẹ Kwara ni wọn ń kanminu lọ́wọ́. 

Aarọ àná tíì ṣe Mọnde là gbọ pé Kabiyesi jáde láyé nínú Ààfin ẹ tó wà ní lágbègbè Igbaja, Kwara South, ìjọba ìbílẹ̀ Ifẹlodun. 

Bí a bá ti gbọ nípa àṣírí ikú tó pá Kabiyesi, a máa muu wá fún-un yín lẹkunrẹrẹ. Ẹ kú ojú lọ́nà. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI