ṢỌỌṢI MFM GBARADA, WỌN F'ÁWỌN ARÁÀLÚ LOUNJẸ, BẸ́Ẹ̀ L'AWỌN ÌJỌBA NÁÀ TÚN GBÀ ORÍṢIRÍṢI Ẹ̀BÙN LỌ́WỌ́ WỌN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, May 5, 2020

ṢỌỌṢI MFM GBARADA, WỌN F'ÁWỌN ARÁÀLÚ LOUNJẸ, BẸ́Ẹ̀ L'AWỌN ÌJỌBA NÁÀ TÚN GBÀ ORÍṢIRÍṢI Ẹ̀BÙN LỌ́WỌ́ WỌN


Kí í ṣe àkọ́kọ́ re e tí ṣọọṣi Orí-Òkè Ina àti Iṣẹ Ìyanu, ìyẹn Mountain of Fire and Miracles Ministry yoo maa f'awọn èèyàn l'ounjẹ àti ẹ̀bùn lásìkò konilegbele yìí.

Ṣùgbọ́n èyí tí wọn tún bẹ̀rẹ̀ laipẹ yìí tún tayọ kọjá afẹnusọ pẹ̀lú bí wọn ṣe fi oúnjẹ bọ àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà jákèjádò.

Bi wọn ṣe fáwọn aráàlú, pàápàá àwọn tó kú díẹ̀ kaato fún n'ipinlẹ Ogun, bẹ́ẹ̀ ni wọn fáwọn èèyàn ni Èkó, Ọ̀yọ́ àti bẹẹ bẹẹ lọ.

Yàtọ̀ sí èyí, wọn tún fún ìjọba ipinlẹ Ogun, Èkó ni mọto pajawiri àti onírúurú irinṣẹ tó lè dẹkun itankalẹ aarun aṣekupani Covid-19. 

Díẹ̀ re e lára àwọn fọto bí wọn ṣe ṣàánú fáwọn èèyàn àti ìjọba.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI