AYẸYẸ ỌJỌ́ ÌBÍ ỌDÚN MARUNDINLAADỌRIN! GÓMÌNÀ ABDULRAZAQ KÍ SẸNETỌ ASHIRU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, June 14, 2020

AYẸYẸ ỌJỌ́ ÌBÍ ỌDÚN MARUNDINLAADỌRIN! GÓMÌNÀ ABDULRAZAQ KÍ SẸNETỌ ASHIRU


Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq tipinlẹ Kwara tí ṣàpèjúwe Sẹnetọ Lọla Ashiru gẹ́gẹ́ bí igi lẹ́yìn ọgbà fún idagbasoke ipinlẹ náà. 

Lónìí ní Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq sọ̀rọ̀ náà nínú atẹjade tó fi kí Sẹnetọ Ashiru fún tí ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún marundinlaadọrin to ń ṣe. 


Gómìnà AbdulRazaq ni Sẹnetọ Ashiru jẹ́ ọ̀kan lára àwọn igi lẹ́yìn ọgbà nínú ìjàkadì Ótógẹ́ nipinlẹ náà. 

Bẹẹ lo gbàdúrà ẹmi gígùn àti àlàáfíà fún Sẹnetọ Ashiru.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI