AYẸYẸ ỌJỌ́ ÌBÍ! PASITỌ ADEBOYE FI ÀDÚRÀ RANṢẸ SÌ PASITỌ KUMUYI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, June 7, 2020

AYẸYẸ ỌJỌ́ ÌBÍ! PASITỌ ADEBOYE FI ÀDÚRÀ RANṢẸ SÌ PASITỌ KUMUYI


Pasitọ àgbà àti alokoso ṣọọṣi Ìràpadà, ìyẹn The Redeemed Christian Church of God, Pasitọ Enoch Adejare Adeboye tí fi àdúrà rabandẹ ranṣẹ sì Oludasilẹ ṣọọṣi Deeper Life Christian Bible Ministry, Pasitọ Williams Fọlọrunṣọ Kumuyi. 

Ọjọ́ Abamẹta, ìyẹn Satide àná ni ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọdún mọkandinlọgọrin Pasitọ Kumuyi, to sì mú kí Pasitọ Adeboye fi àdúrà ranṣẹ sì Baba náà. 

Orí ìkànnì ayélujára tí Twitter ni Pasitọ Adeboye tí kì Pasitọ Kumuyi, níbi tó tún ti gbàdúrà ńlá fun-un. 

Àdúrà àti ìkíni náà lẹ ń wo yii:


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI