Ẹ WO BÍ HAKEEM EFFECT ṢE SỌ ỌDUNLADE ADEKỌLA DI ÒYÌNBÓ ỌSAN GANGAN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, July 2, 2020

Ẹ WO BÍ HAKEEM EFFECT ṢE SỌ ỌDUNLADE ADEKỌLA DI ÒYÌNBÓ ỌSAN GANGAN


Fíìmù kan tí wọn ṣẹ̀ṣẹ̀ parí yíyà rẹ, tí kò sì ní pẹ ẹ jáde síta sórí ìgbà báyìí làwọn èèyàn ti ń fojú sọ́nà láti wo, nibẹ ni gbajugbaja aṣaraloge kan, Hakeem Effect Onilogbo tí sọ Ọdúnladé Adekọla di òyìnbó.

Pupọ àwọn tó rí fọto náà lórí ayélujára lọsẹ to kọjá yìí ló ń ṣe ní kayeefi, tó sì tún ń pá wọn lerin in wí pé afi káwọn lọ wo fíìmù náà.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI