ỌPẸ Ó! DAPỌ ABIỌDUN ṢÍ GBOGBO ILE ÌJỌSÌN SILẸ N'IPINLẸ OGUN, BẸ́Ẹ̀ LO PÀṢẸ Ẹ̀WỌ̀N OṢÙ MẸ́FÀ GBÁKO F'AWỌN TI KO BA LO IBOMU-BOJU - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, July 29, 2020

ỌPẸ Ó! DAPỌ ABIỌDUN ṢÍ GBOGBO ILE ÌJỌSÌN SILẸ N'IPINLẸ OGUN, BẸ́Ẹ̀ LO PÀṢẸ Ẹ̀WỌ̀N OṢÙ MẸ́FÀ GBÁKO F'AWỌN TI KO BA LO IBOMU-BOJU


Gómìnà ìpínlẹ̀ Ogun, Ọmọba Dapọ Abiọdun tí kéde síta wí pé kí gbogbo ilé ìjọsìn káàkiri ìpínlẹ̀ náà ṣì ilẹkun wọn silẹ fún ìjọsìn.

Lónìí ọjọ́ Ẹti, Fraide ni Gomina Abiọdun kéde síta, wí pé bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kẹrìnlá oṣù kẹjọ ọdún yìí ni kí gbogbo ilé ìjọsìn ṣílẹ̀kùn wọn silẹ. 

Bẹ́ẹ̀ lo tún fi àwọn ìlànà kún ọ̀rọ̀ rẹ. 

Síwájú sí í ní Gómìnà Dapọ Abiọdun tún sọ pé àwọn tí ọwọ bá tẹ wí pé wọn kò lo aṣọ ibomu-boju wọn yóò fi ẹ̀wọ̀n oṣù mẹ́fà gbáko ṣe ifajẹ. 

Ẹkunrẹrẹ nbọ laipẹ

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI