WỌN NI ANTHONY JOSHUA ṢETAN LATI JA NIBIKIBI, NIGBAKUGBA LASIKO YII - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, July 29, 2020

WỌN NI ANTHONY JOSHUA ṢETAN LATI JA NIBIKIBI, NIGBAKUGBA LASIKO YII


Eddie Hearn to jẹ ẹni to n gbe Anthony Joshua lo sọrọ naa laipẹ yii wi pe igbaradi Josuha lati ba ẹnikẹni ja ti pari, to si ti ṣetan lati ba ẹda yoowu ja.

Joshua ni ko ti i ba ẹnikẹni ja latigba to ti gba bẹliti ẹni to mọ ẹṣẹẹ gba ju lagbaye, iyẹn HeavyWeight titles ti WBA, IBF ati WBOo, eyi to fi Andy Ruiz Jr gba loṣu kejila ọdun 2019.

AWIKONKO gbọ pe Hearn ti pari pẹpẹ ija kan to pe ni 'Fight Camp' sinu Estate rẹ to wa ni Essex Estate.

Hearn sọ pe b'awọn ko ba tiẹ ri awọn ololufẹ Joshua nibi ija, ija yoo ṣi waye nitori pe o ti ṣe igbaradi to pọ gidi, ko si wahala kankan to ba ja nibẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI