WỌN JU ỌRẸ MEJI S'ẸWỌ ỌDUN MARUN GBAKO LORI ẸSUN EPO RỌBI TI WỌN N JI TA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, July 25, 2020

WỌN JU ỌRẸ MEJI S'ẸWỌ ỌDUN MARUN GBAKO LORI ẸSUN EPO RỌBI TI WỌN N JI TA

Ajọ to n gbogun ti ṣiṣẹ owo ilu kumọkumọ ti fi oju awọn ọrẹ meji ba ile-ẹjọ lori ẹsun gbajuẹ ati jibiti ti wọn lu, adajọ si ti sọ wọn si ẹwọn ọdun marunun-marun-un gbako bayii.

Ọjọ Tọside to kọja yii  ni Oghenovo Emmanuel ati Abdullahi Hassan Bika fóju ba ile-ẹjọ giga kan to wa nipinlẹ Rivers, nibi ti Onidajọ M. L Abubakar ti da ẹjọ wọn.

Ẹsun ti ajọ EFCC fi kan wọn ni pe wọn n ṣowo epo rọbi lona ti ko ba ofin mu, eyi to tako ofin epo rọbi t'ọdun 2004, to si ni ijiya nla ninu.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI