EYI NI ẸKUNRẸRẸ BI ARUN KORONAFAIRỌSI ṢE FI ẸMI Ẹ̀Ẹ́DẸ́GBẸ̀RÚN EEYAN ṢOFO DANU NI NAIJIRIA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, August 5, 2020

EYI NI ẸKUNRẸRẸ BI ARUN KORONAFAIRỌSI ṢE FI ẸMI Ẹ̀Ẹ́DẸ́GBẸ̀RÚN EEYAN ṢOFO DANU NI NAIJIRIA

Awọn ti ko din ni ẹẹdẹgbẹrun ni ajakalẹ arun koronafairọọsi ti ran lọ s'ọrun aremabọ lorilẹ-ede Naijiria.

Ajọ to n ṣabojuto ajakalẹ arun ati aisan ni Naijiria, Nigeria Centre for Disease Control, NCDC lo tu aṣiri naa sita ni alẹ ana, ọjọ Iṣẹgun, Tuside f'awọn eeyan.

Ajọ NCDC sọ pe ọọdun le mẹrin (304) l'awọn ti wọn tun ti ṣawari arun naa lara wọn, to si mu ki apapọ iye awọn to ti kagbako arun naa jẹ ẹgbẹrun lọna ogoji ataabọ (44,433) n'ilẹ Naijiria.

Wọn jẹ ko ye wa pe awọn ẹgbẹrun mejilelọgbọn din diẹ (31,851) ni wọn ti gba ominira kuro ninu arun naa, n'igba ti wọn lawọn ẹẹdẹgbẹrun le ni mẹwaa (910) lo ti jade laye.
Akojọpọ wọn bayii ni:

FCT - 90
Lagos - 59
Ondo - 39
Taraba - 18
Rivers - 17
Borno - 15
Adamawa - 12
Oyo - 11
Delta - 9
Edo - 6
Bauchi - 4
Kwara - 4
Ogun - 4
Osun - 4
Bayelsa - 3
Plateau - 3
Niger - 3
Nasarawa - 2
Kano - 1

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI