IṢẸ-NLỌ! AWỌN ARAALU DANA ARIYA LORI ỌSIBITU IGBO-ORO T'IJỌBA KWARA KỌ PARI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, September 18, 2020

IṢẸ-NLỌ! AWỌN ARAALU DANA ARIYA LORI ỌSIBITU IGBO-ORO T'IJỌBA KWARA KỌ PARIBi ẹ ṣe n ka iroyin yii, ariya rẹpẹtẹ lo n ṣẹlẹ lọwọ nilu Igbo-Oro to wa nijọba ibilẹ Ọffa n'igba ti ijọba ipinlẹ naa labẹ Gomina oloriire wọn, AbdulRahman Abdulrazaq pari atunkọ ọsibitu Igbo-Oro.
 
Lati nnkan bi ọdun meloo kan sẹyin la gbọ pe ọsibitu naa ti wa ni ipo ti ko ba oju mu to, eyi ti ko faaye silẹ f'awọn araalu lati ni eto ilera to p'oju owo.
 
ṣugbọn ni bayii, Gomina Abdulrazaq ti mu idagbasoke igbalode ba ọsibitu naa pẹlu awọn irinṣẹ igbalode ti yoo jẹ k'awọn araalu jẹ igbadun eto ijọba awaarawa.
 
Eyi ni ipo ti ọsibitu naa wa bayii lẹyin ti iṣẹ pari. Iṣẹ Nlọ
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI