AKOBA NLA NI IDAṢẸSILẸ AWỌN OṢIṢẸ YOO JẸ O - GAMA GB'AWỌN OṢIṢẸ KWARA LAMỌRAN - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, October 12, 2020

AKOBA NLA NI IDAṢẸSILẸ AWỌN OṢIṢẸ YOO JẸ O - GAMA GB'AWỌN OṢIṢẸ KWARA LAMỌRAN


Ẹgbẹ kan ti wọn pe ni Gamji Members Association n'ipinlẹ Kwara ti gba awọn oṣiṣẹ n'ipinlẹ naa lamọnran wi pe ki wọn ronu lẹẹmeji ko to di pe wọn gbe igbesẹ naa nitori pe akoba nla ni yoo jẹ.
 
Wọn ni ki i ṣe pe awọn tako awọn nnkan ti wọn n beere lọwọ ijọba, ṣugbọn ki wọn ro o daadaa ko to di pe wọn lọ, ki nnkan ti wọn n ro ma ba a ṣẹlẹ lẹyin ti wọn ba da iṣẹ silẹ.
 
Ẹgbẹ naa ni akoba nla ni yoo jẹ fun gbogbo ọmọ ati olugbe ipinlẹ naa, paapaa awọn oṣiṣẹ funra wọn, idi ree to fi ni ki wọn wa ọna mi in dipo ki wọn lọ si idaṣẹ silẹ.
 
Agbẹnusọ ẹgbẹ naa, Alaaji Abdullahi Yinka Agaka lo sọrọ yii ninu atẹjade to fi sita lọjọ Aiku-Sande ana, eyi ti ẹda rẹ tẹ AWIKONKO lọwọ laipẹ yii. Nibẹ lo ti sọ pe ipinu lati da iṣẹ silẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI