IBANUJẸ ŃLÁ ṢUBÚ LU ALAGBA KỌ́LÁ OYEWỌ, AGBA ÒṢERÉ TÍÁTÀ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, October 12, 2020

IBANUJẸ ŃLÁ ṢUBÚ LU ALAGBA KỌ́LÁ OYEWỌ, AGBA ÒṢERÉ TÍÁTÀ


Káàkiri àgbáyé ni wọn ti ń bá Alàgbà Kọ́láwọlé Oyewọ kẹ́dùn ikú ìyàwó rẹ̀, Yeye Benedicta Oyewọ to kú lópin ọ̀sẹ̀ to kọjá. 

Obìnrin náà là gbọ pé ó jáde láyé lẹ́yìn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà tó ti wà lórí idubulẹ àìsàn rọpa-rọsẹ.


Ọdún 2013 ni wọn yàn Olóògbé yìí gẹ́gẹ́ bí Yeye Balógun tí Ọba-Ilé. 

Ọjọ́ kọkandinlọgbọn sì ọgbọ́n ọjọ́ oṣù yìí ni eto ìsìnkú yóò wáyé. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI