Ìjọba ìpínlẹ̀ Kwara tí fi dá gbogbo àwọn ọmọ àti olùgbé ipinlẹ náà lójú wí pé ìpinnu wọn ní láti ṣe àgbékalẹ̀ eto ọrọ̀ ajé tó yẹ kooro fún ìdàgbàsókè àti ìlọsíwájú.
Ana tí i ṣe Ọjọbọ-Tọside ni Gómìnà AbdulRazaq sọ̀rọ̀ yìí, níbi tó ti ń ṣèlérí atilẹyin fáwọn oníṣòwò kéékèèké káàkiri ipinlẹ náà.
Ó làwọn ń fojú sọ́nà fún rírú eto ọrọ ajé ipinlẹ Èkó, káwọn sì máa pá owó tó tó mílíọ̀nù márùndinlogoji (N35b) náírà loṣu.
No comments:
Post a Comment