NÍTORÍ OYINDASỌLA, GÓMÌNÀ ABDULRAZAQ DÚPẸ́ LỌ́WỌ́ ÀÀRẸ BUHARI - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, October 1, 2020

NÍTORÍ OYINDASỌLA, GÓMÌNÀ ABDULRAZAQ DÚPẸ́ LỌ́WỌ́ ÀÀRẸ BUHARI


Gómìnà AbdulRahman AbdulRazaq tí ìpínlẹ̀ Kwara tí gbé oṣuba káre fún Ààrẹ Muhammadu Buhari lórí bo ṣe yàn ọkàn lára àwọn ọmọ ìpínlẹ̀ Kwara, Ọmọwe Rẹmi Oyindasọla gẹ́gẹ́ bí í alaga fún ileeṣẹ tó ń rí sọ̀rọ̀ àwọn òṣìṣẹ́-fẹyinti, ìyẹn National Pension Commission {PENCOM} 

AbdulRazaq ni ẹni tí ipò náà tọ si ni Ààrẹ Buhari yàn síbẹ̀, tó sì lòun ni igbagbọ wí pé Ọmọwe Oyindasọla kò ní í ja ìjọba orílẹ̀ èdè Nàìjíríà kulẹ̀. 

Ọmọ bíbí ìlú Ọffa náà là gbọ pé àwọn ipa tó ti ko lẹka eto ọrọ̀ aje orílẹ̀ èdè yìí kò ṣeé fọwọ́ rọ́ sẹ́yìn. 

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI