O MA ṢE O: IYAALE ILE AT'AWỌN ỌMỌ RẸ KU SÍNU ṢỌỌBU L'ABUJA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Saturday, October 10, 2020

O MA ṢE O: IYAALE ILE AT'AWỌN ỌMỌ RẸ KU SÍNU ṢỌỌBU L'ABUJA


Kayeefi ni iku iyaale ile kan, at'awọn ọmọ rẹ ṣi n jẹ f'awọm ara agbegbe Kubwa titi di asiko ta a pari iroyin yii.
 
Ọjọ Ẹti, Fraide ana n'iṣẹlẹ kayeefi naa waye nígba ti wọn sọ pe ṣe ni wọn dee de ri oku awọn eeyan naa ninu ṣọọbu wọn, iyẹn nilu Abuja.
 
Igba ti wọn l'awọn ara agbegbe naa ko tete ri awọn to wa ninu ṣọọbu naa lati ṣilẹkun lo mu ki ara fu wọn, ti wọn si lọ fi to awọn ọlọpaa leti. Awọn ọlọpaa la gbọ pe wọn ja ilẹkun naa, ti wọn fi ri oku wọn nilẹ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI