Ibi iwọde ifẹhonu han t'awọn eeyan n ṣe kaakiri agbaye nipa wi pe ki wọn ko awọn ọlọpaa kogberegbe, iyẹn SARS kuro n'ilẹ, eyi ti wọn pe ni #ENDSARS ti wọn n ṣe lọwọ la gbọ pe awọn ọlọpaa ti yinbọn pa ọdọmọkunrin naa.
Wọn ni ṣe l'awọn ọlọpaa dabọn bolẹ f'awọn eeyan nibi ti wọn ti n ṣe iwọde naa lonii, tibọn naa si ba ọmọkunrin yii, to si ku loju ẹsẹ.
No comments:
Post a Comment