AWỌN ỌMỌ IJỌ WOLII ỌLADELE GENESIS ṢE ISIN ỌPẸ NLA - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, November 22, 2020

AWỌN ỌMỌ IJỌ WOLII ỌLADELE GENESIS ṢE ISIN ỌPẸ NLA


Pupọ awọn eeyan kaakiri agbaye ni wọn ti n ro pe isin ko ni i waye lonii ọjọ Sannde ninu ṣọọṣi ṣẹlẹ ti Genesis Global to jẹ ti Wolii Israel Ọladele Ogundipẹ lori awọn awuyewuye kan to n lọ nigboro nipa ẹ.
 
 
Ṣugbọn ọrọ ko ri bẹẹ rara tori pe Ọlọrun ju ẹda lọ l'awọn ọmọ ijọ rẹ fi ṣe, ti wọn si dupẹ lọwọ Ọlọrun pe o ṣi n jọba lori itẹ. 
 
Diẹ ree lara bi isin ologo ṣe lọ ninu ijọ naa.


Genesis Global

Genesis Global

Genesis Global


Genesis Global
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI