{FỌ́TÒ} Ọ̀Ọ̀NI ILÉ IFẸ̀ ṢE ÀBẸ̀WỌ̀ SI WÒLÍÌ ESTHER ÀJÀYÍ ÀTI ỌKỌ RẸ̀ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, November 11, 2020

{FỌ́TÒ} Ọ̀Ọ̀NI ILÉ IFẸ̀ ṢE ÀBẸ̀WỌ̀ SI WÒLÍÌ ESTHER ÀJÀYÍ ÀTI ỌKỌ RẸ̀


Ìyàlẹ́nu ńlá gba a lo jẹ́ fún gbajumọ wòlíì nnì, Wòlíì Esther Ajayi àti ọkọ rẹ̀, Ọmọwe Ademuyiwa Ajayi nígbà tí Ọọni Ilé Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi bá wọn lálejò. 

Fúnra Esther Àjàyí lo gbé e sórí ìkànnì ayélujára wí pé inú òun dùn láti gba Ọọni Ogunwusi, Ọjaja kejì lálejò nílé òun. 

Fọto abẹwo náà rèé:


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI