IPI BU ỌWỌ LU OLORIEWE ADEDOYIN GẸGẸ ỌKAN LARA AWỌN IGBIMỌ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Tuesday, November 3, 2020

IPI BU ỌWỌ LU OLORIEWE ADEDOYIN GẸGẸ ỌKAN LARA AWỌN IGBIMỌIjọba ipinlẹ Kwara labẹ akoso Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti gbe oṣuba rabandẹ fun ajọ kan ti wọn pe ni International Press Council lori bi wọn ṣe bu ọwọ lu Ọgbẹni Oloriewe Raheem Adedoyin gẹgẹ bi ọkan lara awọn igbimọ iṣakoso wọn.
 
Gomina AbdulRazaq n'igba to n fi idunnu rẹ han sọ pe  ọkunrin naa kaju oṣuwọn, ayi pe awọn ipa to ti ko lagboole oniroyin ko ṣe e fọwọ rọ ti sẹyin, ati pe manigbagbe l'awọn ipa to ti ko.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI