ỌPẸ O! OMI ALADUN TUNTUN WỌ IPINLẸ OGUN 'JOYOM WATER' L'ORUKỌ Ẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, December 3, 2020

ỌPẸ O! OMI ALADUN TUNTUN WỌ IPINLẸ OGUN 'JOYOM WATER' L'ORUKỌ Ẹ


Bi ẹ ṣe n ka iroyin yii, ko si omi meji t'awọn eeyan tun n beere fun bayii bi ko ṣe Omi aladun nni ti wọn pe ni JOYOM WATER, eyi ti ileeṣẹ Joyom Enterprises n ṣe jade.
 
Ọbada to wa loju ọna Eko si Abẹokuta ni ileeṣẹ Joyom Exterprises wa, ta a si gbọ pe ko si ileeṣẹ to tobi to omi naa ni gbogbo agbegbe yii.
 
Ayika to mọ toni, pẹlu imọ ẹrọ igbalode ni wọn fi n ṣe omi wọn jade, ti wọn si tun gba aṣẹ ati ontẹ lati ọdọ ajọ to n ṣagbeyẹwo ounjẹ ati oogun lorilẹ-ede yii, iyẹn National Agency for Food Drug and Administration Control (NAFDAC).

Omi naa tobi ju awọn eyi to wa nita tẹlẹ ati asiko yii lọ, to si dara lẹnu fun mimu ati idana ati ohun gbogbo ti wọn n lo omi fun.

Anfaani wa lati jẹ alagbata Omi Joyom Water kaakiri ipinlẹ Ogun. E le pe awọn nọmba ileeṣẹ naa: 08079460722, 07015109640




 

Diẹ lara awọn ẹri t'awọn eeyan n sọ nipa omi Joyom Water

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI