Idunnu ṣubu lu ayọ: Watford peregede wọ idije Liigi Premier - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, April 25, 2021

Idunnu ṣubu lu ayọ: Watford peregede wọ idije Liigi Premier


Lanaa ti ṣe Sátidé ni ikọ ẹgbẹ agbabọọlu Watford peregede wọnú idije Liigi Premier, ìyẹn Premier League l'ẹyin ti wọn dojú ìkọ ẹgbẹ agbabọọlu Millwall bọlé pẹlu aami ayo kan si odo.

Bi wọn ṣe borí nínú ifigagbaga náà ti fi hàn daju pe ìkọ ẹgbẹ agbabọọlu Watford ti peregede lati kopa ninu idije Liigi Premier, ìyẹn Premier League.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI