Ọba Almaroof Adekunle Magbagbeọla Olumoyerọ keji, Olufọn tilu Ifọn ni ipinlẹ Ọṣun ti wàjà.
Ana ti í ṣe ọjọ Isẹgun ìyẹn Tusidee ni Ọba Magbagbeọla Olumoyerọ keji wàjà lẹyìn àìsàn ránpẹ́ ti wọn lo o da kabiyesi dubulẹ.
Gbogbo àwọn ọmọ ati olugbe ilu Ifọn ni wọn ti n ba mọlẹbi Kabiyesi kẹdun bi ọba náà ṣe wàjà.
No comments:
Post a Comment