AbdulRazaq ṣabẹwo si ọsibitu ti wọn ti n ṣiṣẹ abẹ oju ati eyin ti wọn n kọ lọwọ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, June 25, 2021

AbdulRazaq ṣabẹwo si ọsibitu ti wọn ti n ṣiṣẹ abẹ oju ati eyin ti wọn n kọ lọwọ


Gomina ipinleẹ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq ti ṣe abẹwo si ọsibitu ti wọn ti n ṣiṣẹ abẹ fun oju ati eyin, eyi ti wọn n kọ lọwọ niluu Ilọrin.
 
Ọsibitu ijọba, iyẹn Jẹnẹra to wa niluu Ilọrin ni wọn n kọ ọsibitu yii si, fun igbadun awọn araalu patapata.
 
Neurosurgical Centre, Eye Clinic and Dental Centre lawọn oloyinbo n pe iru ọsibitu bayii. Gbogbo ọmọ ati olugbe ipinlẹ naa la gbọ pe wọn yoo jẹ anfaani l'ọsibitu yii bi iṣẹ ba ri.
 

Lara awọn ileri gomina lati mu irọrun de ba eto ilera ni kikọ ọsibitu yii.
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI