Alebioṣu di Ọba Ajaṣẹ-Ipo tuntun ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Monday, June 21, 2021

Alebioṣu di Ọba Ajaṣẹ-Ipo tuntun ni KwaraIjọba ipinlẹ Kwara lonii ti i ṣe ọjọ Aje, Mọnde ti fun Ọba Ismail Yahaya Alebioṣu niwe aṣẹ gẹgẹ bi Olupo tilu Ajaṣẹ-Ipo tuntun. Idunnu nla lo si ti ṣubu lu gbogbo awọn araalu naa lakooko ti a pari iroyin yii.

Nibi ipade rampẹ kan ti wọn ṣe lọgba ileeṣẹ ijọba ipinlẹ naa ni kọmiṣanna fọrọ ijọba ibilẹ, idagbasoke agbegbe ati ye jijẹ nipinlẹ naa, Ayawora-Ile Aliyu Saifuddeen ti fa iwe aṣẹ naa le Ọba Alebioṣu lọwọ.
 
Saifuddeen sọ pe bi wọn ṣe yan Ọba Yahaya Alebioṣu naa lọ ni ibamu, ati pe ẹni ti ipo naa tọ si ni wọn gbe e fun.
 


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI