Baba Ijẹṣa foju ba ile ẹjọ lonii, e wo bi wọn ṣe yẹyẹ ẹ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, June 16, 2021

Baba Ijẹṣa foju ba ile ẹjọ lonii, e wo bi wọn ṣe yẹyẹ ẹ


Lonii ti i ṣe Ọjọru, Wẹside ni gbajugbaja oṣere tiata, to tun jẹ adẹrinpoṣonu nni, Ọlanrewaju James Omiyinka ti pupọ awọn ololufẹ rẹ mọ si Baba Ijẹṣa foju ba ile ẹjọ.

Ile ẹjọ Majisreeti yo wa ni Yaba, niluu Eko ni Baba Ijẹṣa ti lọọ kawọ pọyin rojọ lori ẹsun aṣemaṣe ti wọn fi kan an.

Diẹ ree lara awọn fọto bi wọn ṣe daa jokoo silẹ bi ọdaran:

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI