Ó tán o! Wọ́n n'Ìgbòho ti fojú ba ilé-ẹjọ́ ní Kútọnu, ẹ tún gbọ́ ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn-án - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, July 21, 2021

Ó tán o! Wọ́n n'Ìgbòho ti fojú ba ilé-ẹjọ́ ní Kútọnu, ẹ tún gbọ́ ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn-án


Iroyin to tẹ AWIKONKO lọwọ bayii ni pe wọn ti foju olori ajijangbara ilẹ Yoruba, Oloye Sunday Adeniyi Adeyẹmọ, ti awọn eeyan tun mọ si Sunday Igboho ba ile ẹjọ

A gbọ pe ile-ẹjọ giga tilẹ olominira Benin ti Rue 447 (Judicial Service Benin, Rue 447, Cotonou, Benin 02BP2004) ni wọn foju Sunday Igboho ba laarọ oni, Ọjọru, Wẹsidee.

Ko si ẹsun meji ta a gbọ pe wọn fi n kan Igboho lọwọlọwọ bayii, bi ko ṣe pe o fẹẹ lo ayẹderu iwe irinna orilẹ-ede Naijiria lati fi gba Benin salọ si Germany.

Ẹkunrẹrẹ iroyin n bọ laipẹ.

1 comment:

PÍN-IN KÁÀKIRI