Akérédolú, Fáyẹmí ṣàbẹ̀wò si Tinubu ni London lónìí - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Wednesday, August 25, 2021

Akérédolú, Fáyẹmí ṣàbẹ̀wò si Tinubu ni London lónìí


Gomina ipinlẹ Ondo ati Ekiti, Rotimi Akeredolu ati Kayọde Fayẹmi ti ṣe abẹwo si Aṣiwaju ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC, Bọla Ahmed Tinubu.

Oni, Ọjọru, Wẹside lawọn gomina mejeeji yii ṣe abẹwo naa si Tinubu, ẹni to lọ fun ara rẹ ni isinmi niluu Oyinbo.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI