Wọ́n níkú Dominic, alága ẹgbẹ́ òṣèlú PDP l'Ékòó kìí ṣojú lásán - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Wednesday, August 25, 2021

Wọ́n níkú Dominic, alága ẹgbẹ́ òṣèlú PDP l'Ékòó kìí ṣojú lásán


Ki i ṣe iroyin tuntun mọ wi pe alaga ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP nipinlẹ Eko, Dọkita Dominic Adegbọla jade laye.

Iroyin to tẹ AWIKONKO lọwọ nipa iku Dọkita Dominic Adegbọla ni pe arun Korona, iyẹn COVID-19 lo ṣeku pa a, gẹgẹ bi akọwe ipolongo ẹgbẹ naa Taofik Gani ṣe ṣalaye fawọn akọroyin lonii, Ọjọru, Wẹside.
 
Adegbọla la gbọ pe o jẹ dọkita ọsibitu Santa Maria to wa l'Ekoo, to si ti fi ara rẹ jin nipa iwa ififunni.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI