Buraimọh gbe oṣuba kare fun ileeṣẹ redio Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ
Saturday, August 21, 2021

Buraimọh gbe oṣuba kare fun ileeṣẹ redio Kwara


Kọmiṣanna fọrọ eto ikanisira-ẹni nipinlẹ Kwara, Arabinrin Ọlaitan Abọsẹde Buraimọh, ti gbe oṣuba kare fun ileeṣẹ redio tipinlẹ Kwara, lori ọna ti wọn n gba gbe iṣẹ iroyin ati igbohunsafẹfẹ larugẹ kaakiri agbaye.
 
Bẹẹ lo tun gbe oriyin fawọn oṣiṣẹ ileeṣẹ redio naa fun iṣẹ takuntakun ti wọn n ṣe lati maa fi bo ṣe n lọ laujọ to awọn araalu leti loore-koore.
 
 has commended the management and staff of the state owned Nibi abẹwo ti kọmiṣanna naa ṣe lọ sileeṣẹ redio ọhun lo ti lu wọn lọgọ ẹnu.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI