AbdulRazaq ṣàbẹ̀wò ibánikẹ́dùn si Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn, Dàpọ̀ Abíọ́dún - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, September 9, 2021

AbdulRazaq ṣàbẹ̀wò ibánikẹ́dùn si Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn, Dàpọ̀ Abíọ́dún


Gomina ipinlẹ Kwara, AbdulRahman AbdulRazaq lana, Ọjọru, Wẹside lo ti ṣe abẹwo ibanikẹdun si gomina akẹgbẹ rẹ, Dapọ Abiọdun tipinlẹ Ogun lori iku baba rẹ.

Nibi abẹwo naa ni gomina AbdulRazaq ti gb'adura wi pe ki Ọlọrun tẹ baba naa si afẹfẹ rere, bẹẹ ni ki Ọlọrun fun gbogbo awọn mọlẹbi yooku ni ẹmi gigun ati alaafia.No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI