Gbajúmọ̀ olórin Fújì nnì, Baby Barrister ti kú o - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Tuesday, September 21, 2021

Gbajúmọ̀ olórin Fújì nnì, Baby Barrister ti kú o


Gbajugbaja olorin Fuji nni to n kọrin bi Oloogbe Sikiru Ayinde Barrister, iyẹn Alaaji Kabiru Kẹhinde ti ọpọ awọn ololufẹ rẹ mọ si Baby Barrister ti jade laye.

Alẹ ana, ọjọ Aje, Mọnde ni iroyin fi to wa leti sọ pe ọkunrin naa jade laye nile ẹ to wa niluu Ibafo, ipinlẹ Ogun.

Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI