Gbajugbaja onkọrin nni, Oloye Sunday Adeniyi Adegẹye ti ọpọ awọn eeyan mọ si Sunny Ade ti padanu iyawo rẹ, Arabinrin Ajọkẹ Risikat Adegẹye.
Bo tilẹ jẹ pe a ko tii gbọ nipa kulẹkulẹ aṣiri iku to pa obinrin naa, ṣugbọn ti a gbọ pe lẹyin aisan rampẹ lo jade laye.
Ẹkunrẹrẹ iroyin n bọ laipẹ.
No comments:
Post a Comment