Ìjọba Kwara àti ilé-iṣẹ́ TVS ṣì n tẹ̀síwájú láti ṣe ìrànwọ́ fáwọn oní Kẹ̀kẹ́ Márúwá - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, October 31, 2021

Ìjọba Kwara àti ilé-iṣẹ́ TVS ṣì n tẹ̀síwájú láti ṣe ìrànwọ́ fáwọn oní Kẹ̀kẹ́ Márúwá


Lati tubọ daabo boẹmi ati dukia awọn araalu, ijọba ipinlẹ Kwara ati ileeṣẹ TVS to n ṣe Kẹkẹ Maruwa ati Ọkada ti sọ pe awọn ko nii dawọ duro lati maa ṣe atunṣe to ba yẹ lawọn Kẹkẹ Maruwa ọgọrun-un ti wọn gbe sita fawọn araalu laipẹ yii.

AWIKONKO gbọ pe latigba ti wọn gbe awọn Kẹkẹ naa fawọn ti yoo maa wa wọn nijọba ipinlẹ Kwara ti sọ pe awọn ayẹwo ati atunṣe to ba yẹ gbọdọ waye lori Maruwa kọọkan, lati din ijamba oju popona ku.
 
Bi ayẹwo ati atunṣe naa ṣe n tẹsiwaju, diẹ ree lara awọn iṣẹ to n lọ lọwọ.
 
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI