Ìjọba Kwara ró àwọn aráàlú lágbára lárà-ọ̀tọ̀ - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Friday, October 15, 2021

Ìjọba Kwara ró àwọn aráàlú lágbára lárà-ọ̀tọ̀


L'Ọjọbọ, Tọside ana, nijọba ipinlẹ Kwara labẹ Gomina AbdulRahman AbdulRazaq tun fitan tuntun balẹ nipa riro awọn araalu lagbara lọna ara-ọtọ.

Pupọ awọn oniṣẹ ọwọ to wa kaakiri ipinlẹ naa ni wọn jẹ anfaani gbigba awọn irinṣẹ ti yoo mu iṣẹ wọn rọrun nilu Ilọrin.

Nigba to n pin awọn ẹbun naa fun wọn, igbakeji gomina, Kayọde Alabi sọ pe lojuna lati mu ileri ṣẹ nijọba ṣe ṣagbekalẹ eto iranlọwọ yii fun gbogbo awọn oniṣẹ ọwọ ati olokoowo kekeekee.
 
Lara awọn ẹbun ti wọn fi tọrẹ ni Maṣiini iranṣọ, ẹrọ ijata, owo atawọn nnkan mi in.
 No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI