Ìgbéyàwó Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ Ọba Ògúnwùsì àti olorì rẹ̀ dàrú lọ̀sán gangan - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, December 23, 2021

Ìgbéyàwó Ọọ̀ni Ilé-Ifẹ̀ Ọba Ògúnwùsì àti olorì rẹ̀ dàrú lọ̀sán gangan


Olori Ṣikẹkunọla Naomi Adeyẹye ti kede sita wi pe oun ti kọ Ọọni Ile Ifẹ, Ọba Babatunde Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi silẹ, ati pe oun kọ lati maa jẹ Olori Ọọni tabi olori nile Ofẹ.

Naomi sọ pe oun ko le fara da awọn wahala toun n koju laafin Ọọni Ile Ifẹ mọ, ti oun si nilo lati fi ọkan ara oun balẹ.

Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ n bọ laipẹ

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI