Kwara: ìpínlẹ̀ àlàáfíà àti ìfọ̀kànbalẹ̀ - Gómìnà Babangana Zulum - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, December 13, 2021

Kwara: ìpínlẹ̀ àlàáfíà àti ìfọ̀kànbalẹ̀ - Gómìnà Babangana Zulum


Gomina ipinlẹ Borno, Ọjọgbọn Babagana Zulum ti ṣapejuwe ipinlẹ Kwara gẹgẹ bi ipinlẹ ti alaafia, iṣọkan ati ifọkanbalẹ n jọba, koda, to lo kọja afẹnuroyin.
 
O tun sọ pe kii ṣe ifọkanbalẹ  ati alaafia nikan lo n jọba nipinlẹ naa, bi ko ṣe pe idagbasoke alailẹgbẹ lo n ṣẹlẹ, eyi ti yoo gba awọn ileeṣẹ nla-nla lati wọle wa.

Gomina Zulum sọrọ yii nibi ayẹyẹ ikẹkọọjade ẹlẹẹkẹjọ ati ikẹsan-an iru ẹ to waye ni fasiti ipinlẹ Kwara to wa ni Malete, ipinlẹ naa lopin ọsẹ to kọja yii.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI