Àlàó Àkálà náà ti kú ooooo - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, January 12, 2022

Àlàó Àkálà náà ti kú ooooo


Gomina tẹlẹri nipinlẹ Ọyọ, Christopher Alao Akala ti jade laye lẹni ọdun mọkanlelaadọrin (71), lonii Ọjọru, Wẹsidee.

Akala, ọmọ bibi ilu Ogbomọṣọ naa la gbọ pe o jade laye, ninu ile ẹ to wa nilu Ogbomọṣọ.

Lara awọn to fi iroyin naa to wa leti sọ pe ṣe ni wọn ba oku Akala lori bẹẹdi, lẹyin ọpọlọpọ ọdun ti aisan kan ti n ba a finra.

Gomina Ṣeyi Makinde ti fi lẹta ibanikẹdun ranṣẹ si awọn mọlẹbi ati gbogbo ọmọ ipinlẹ Ọyọ jakejado.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI