Nítorí ìmọ́tótó, àwọn aráàlú gbóṣùbà káre fún Gómìnà AbdulRazaq - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Wednesday, January 12, 2022

Nítorí ìmọ́tótó, àwọn aráàlú gbóṣùbà káre fún Gómìnà AbdulRazaq


Ṣe lo dabi ẹni pe awọn angẹli imọtoto balẹ silu Ilọrin, ipinlẹ Kwara nigba ti awọn oṣiṣẹ eto ayika ati agbegbe bẹrẹ sii ko awọn idọti to wa kaakiri opopona danu.

Eyi lo mu ki ori awọn araalu gbe oṣugbba kare fun Gomina AbdulRahmanhg AbdulRazaq ti ipinlẹ naa lẹyin aṣẹ rẹ.

AWIKONKO gbọ pe ṣe lawọn araalu sọ gbogbo ẹgbẹ opopona di ile idalẹnu si, eyi to ṣee ṣe ko ṣe akoba fun ilera awọn araalu.

Ni bayii, ijọba ti sọ pe otogẹ fun dida idọti sawọn agbegbe kaakiri opopona ati igberiko baakiri.



No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI