Owó Oṣù Tuntun: Àwọn aṣòfin ìpínlẹ̀ Kwara gbé òṣùbà káre fún AbdulRazaq - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Thursday, January 6, 2022

Owó Oṣù Tuntun: Àwọn aṣòfin ìpínlẹ̀ Kwara gbé òṣùbà káre fún AbdulRazaq


L'Ọjọru, Wẹsidee ana lawọn aṣofin ipinlẹ Kwara gbe oṣuba kare fun Gomina AbdulRahman AbdulRazaq lori owo oṣu tuntun tijọba fẹẹ maa san fawọn oṣiṣẹ rẹ.

Owo oṣu tuntun naa la gbọ pe o jẹyọ ninu eto iṣuna oni biliọnu mọkandinlaadọwa (₦189.4b) ọdun 2022 ti a wa yii.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI