Iroyin yajoyajo to tẹ wa lọwọ laipẹ yii sọ pe wọn ti tu Oloye Sunday Adeyẹmọ, ti ọpọ awọn eeyan mọ si Sunday Igboho silẹ lọgba ẹwọn orileede Bẹnin.
Ọjọgbọn Banji Akintoye la gbọ pe wọn fi Igboho silẹ fun lonii, ọjọ Aje, Mọnde.
Gẹgẹ Ọgbẹni Maxwell Adelẹyẹ to jẹ akọwe ẹgbẹ Ilana Ọmọ Oodua ṣe sọ, o ni bi wọn ṣe fi Igboho silẹ je aṣeyọri fun wọn.
Ẹkunrẹrẹ iroyin naa n bọ laipẹ.
No comments:
Post a Comment