Itan ṣoki nipa 'ọmọ eniyan' ti mo gbọ lẹnu Ọbasanjọ dabi pe mo wa ni yara ikẹkọọ - Kẹmi Adeọṣun - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, May 2, 2022

Itan ṣoki nipa 'ọmọ eniyan' ti mo gbọ lẹnu Ọbasanjọ dabi pe mo wa ni yara ikẹkọọ - Kẹmi Adeọṣun


Minisita f'ọrọ eto iṣuna tẹlẹri lorileede Naijiria, Arabinrin Oluwakẹmi Adeọṣun ti sọ pe asiko perete toun lo lọdọ Aarẹ tẹlẹri lorileede yii, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ dabi eni pe oun wa ninu yara ikẹkọọ awọn ọjọgbọn ni.

Kẹmi Adeọṣun to kọwe fipo rẹ silẹ gẹgẹ bi Minisita f'ọrọ eto iṣuna lọdun diẹ sẹyin lo sọ eyi di mimọ ni kete to kuro nile Ọbasanjọ to wa niluu Abẹokuta, ipinlẹ Ogun, iyẹn nibi to ti lọ ṣe abẹwo si i lọjọ Aiku, Sannde ana.

O ni inu oun dun gidigidi wi pe baba sọ itan ṣoki nipa ọrọ ọmọ eniyan ati ile aye foun, eyi to tun ṣi oun niye si iNo comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI