Ààrẹ Buhari búra fún Ariwoọlá gẹ́gẹ́ bi adájọ́ àgbà tuntun (Fọ́tò) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Monday, June 27, 2022

Ààrẹ Buhari búra fún Ariwoọlá gẹ́gẹ́ bi adájọ́ àgbà tuntun (Fọ́tò)


Ààrẹ Muhammadu Buhari ti búra fún adájọ́ Olukayode Ariwoola gẹ́gẹ́ bíi adelé adájọ́ àgbà Nàìjíríà.

Ariwoola, tó rọ́pò adájọ́ Muhammad Tanko tó kọ̀wé fipò sílẹ̀, yóò di ipò náà mú gẹ́gẹ́ bíi adelé adájọ́ àgbà.









No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI