Mo ni ẹni ti Tinubu le lo gẹgẹ bi igbakeji rẹ - Gbajabiamila - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, June 27, 2022

Mo ni ẹni ti Tinubu le lo gẹgẹ bi igbakeji rẹ - Gbajabiamila


Abẹnugọn ile igbimọ aṣofin kekere lorileede yii, Ọnarebu Fẹmi Gbajabiamila ti sọ pe oun ni ẹnikan to kaju oṣuwọn, toun le fun oludije s'ipo aarẹ orileede yii labẹ asia ẹgbẹ oṣelu
All Progressives Congress (APC), Aṣiwaju Bọla Ahmẹd Tinubu lati lo gẹgẹ bi igbakeji rẹ.
 
Gbajabiamila lo sọ eyi nibi ayẹyẹ ọjọ ibi ọgọta ọdun rẹ to ṣe laipẹ yii.
 
Ṣaaju asiko yii ni Tinubu ti fi orukọ Ibrahim Kabir Masari ṣọwọ si ajọ eleto idibo gẹgẹ bi gbakeji rẹ, lati le fi ba gbedeke ti ajọ naa fi sita.


No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI