Ẹ wo àwọn gómìnà APC tó tẹ̀lè Tinubu lọ s'Ékòó (Fọto) - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, June 20, 2022

Ẹ wo àwọn gómìnà APC tó tẹ̀lè Tinubu lọ s'Ékòó (Fọto)


L'opin ọsẹ ti a ṣẹṣẹ lo tan yii ni awọn gomina l'ẹgbẹ oṣelu All Progressives Congress, APC lorileede Naijiria ṣe abẹwo si Aṣiwaju ẹgbẹ naa, Bọla Ahmed Tinubu nile rẹ to wa niluu Eko.

A gbọ pe abẹwo ti wọn ṣe si i ni lati tubọ ki ku oriire bo ṣe di ọmọ oye fun ipo aarẹ orileede yii ninu idibo apapọ to n bọ l'ọdun 2023.

Lara awọn gomina to wa nibẹ ni AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara, toun naa ko gbẹyin nibi abẹwo ọhun.

Diẹ ree lara awọn fọto bi nnkan ṣe lọ.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI