Bọ́ìsì ṣì ni mí - Olúwòó ti ìlú Ìwó l'Ọ́ṣun - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Monday, July 4, 2022

Bọ́ìsì ṣì ni mí - Olúwòó ti ìlú Ìwó l'Ọ́ṣun


Ọpọ àwọn to ri awọn fọto aramanda ti Oluwo t'iluu Iwo ni ipinlẹ Ọṣun, Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi, Telu kin-ni-in gbe jade s'ori ikanni ayelujara ti fesibuuku rẹ laipẹ yii lo n ṣe ni kayeefi.

Ẹrin ati awada ti wọn fi n ṣe, ti wọn si n sọ pe Kabiyesi naa ko fẹẹ di arugbo, ati pe o tun ranti igba to ṣi wa ni ọdọ, iyẹn Bọisi.


Odu ni Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi laaarin awọn ọba alaye nilẹ Yoruba, koda ti ẹnu maa n kun-un l'awọn igba kan, lori awọn ọrọ re ti ki i ba erongba awọn yooku mu nigba miran.

Kaaaaaaabiyeeeeesiiiii oooooooo
No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI