Oriire nla! Awọn oṣiṣẹ ati oṣiṣẹfẹyinti gba owo oṣu kẹfa kikun ni Kwara - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Thursday, July 7, 2022

Oriire nla! Awọn oṣiṣẹ ati oṣiṣẹfẹyinti gba owo oṣu kẹfa kikun ni Kwara


Lasiko ti a ṣakojọpọ iroyin yii tan, inu idunnu ati l'awọn oṣiṣẹ, ati oṣiṣẹfẹyinti kaakiri ipinlẹ Kwara wa, lori bi ijọba ṣe san gbogbo owo oṣu wọn lai ku ẹyọkan.
 
A gbọ pe awọn oṣiṣẹ SUBEB, ijọba ibilẹ ati oṣiṣẹfẹyinti patapata kaakiri ijọba ibilẹ mẹrindinlogun to wa n'ipinlẹ naa ni wọn gba owo oṣu kẹfa to kọja yii

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI