Bi a ba fẹ idagbasoke, a fi ka ro awọn ọdọ lagbara - AbdulRazaq - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ

Sunday, August 14, 2022

Bi a ba fẹ idagbasoke, a fi ka ro awọn ọdọ lagbara - AbdulRazaq


Gomina AbdulRahman AbdulRazaq ti ipinlẹ Kwara ti jẹ ko di mimọ pe bi ipinlẹ tabi orileede kan ba n fẹ ilọsiwaju ati idagbasoke to lọọrin, afi ki wọn ṣe ro awọn ọdọ lagbara, ki ilu le ni ọjọ iwaju rere.
 
AbdulRazaq to ni awọn ọdọ ni ọjọ iwaju orileede sọrọ yii lasiko to n b'awọn ọdọ yọ fun ti ayẹyẹ ọjọ awọn ọdọ lagbaye.
 






No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI