Nitori iwa ọmọluabi ati aanu: Awọn araalu rọ'jo adura le Aderionkun lori l'Abẹokuta - IROYIN AWIKONKO

LÉRÉFÈÉ


Sunday, August 21, 2022

Nitori iwa ọmọluabi ati aanu: Awọn araalu rọ'jo adura le Aderionkun lori l'Abẹokuta


Beeyan ba wa ninu ọja Kutọ to gbajumọ daadaa niluu Abẹokuta l'ọsan oni, ọjọ Aiku, Sannde, yoo  mọ pe ko si nnkan to kọja iwa rere ti Yoruba n pe ni ẹṣọ eniyan.

Gbogbo awọn ara ọja Kutọ la gbọ pe wọn bẹrẹ sii gbadura ni kete ti Oloye Olumide Aderinokun, Oludije s'ipo ile igbimọ aṣofin agba lorileede yii labẹ asia ẹgbẹ oṣelu Peoples Democratic Party, PDP wọle sibẹ lati wo alaafia wọn.

Ohun ti ọpọ awọn ọlọja n sọ ni pe awọn ti n gbọ orukọ ọkunrin naa tipẹ, nipa iwa rere ati ẹyinju aanu.

No comments:

Post a Comment

PÍN-IN KÁÀKIRI